Kabiesi rę The heaven declare the glory of the Lord And the firmament showeth his hand work Ojo dee ojo n’fohun Oru dee oru n’fi imo han Ko si ohun kan tabi ede kan nibiti ako gbo iro wan Iro wan la gbogbo aiye ja Ati oro won de opin re Chorus: Kabiesi rę ×3 Akikitan olodumare Kabiesi rę x3 Akikitan olodumare Solo1: And we declare your majesty King of zion, God of all angels Great are your Wonderful works (babami) Akikitan olodumare (Tori o) Awon Angeli lorun won ki o (Kabiesi) Egbaagbeje irawo won foribale Awon agbagba merinlelogun Pelu eda alaye merin won ke mimo si o ooo Ologo imole A see Kabiesi oo Back to chorus Solo 2: Kabiesi oooo Aditu awon Eni mimo ooo Atabatubu eledumare Monamona tin shoju orun maroro maroro Amo roro Ala ro ro o Tan to gbe na wo ju re ooo Ekun oko
- Release Date:June 6, 2023